Sunday 8 June 2014

ORO OLORUN ATI ADURA

AKORI:  AABO LORI IDILE – Eccl. 10:8
Eniti o wa iho ni yio bo sinu re, ati eniti o si nja ogba tutu, ejo yio sib u u san
-        Enyin enia Olorun, o se Pataki lati dabobo ile/idile re
-        Opolopo ni awon ipa lati ode (ita) to ma dide si awon idile Kristieni.
-        O se Pataki lati se ayewo ipile ti idile wa duro le lori
-        Se idile wa kuro lori ife (will) Olorun bi?
-        Se ati gbogoje ohun kan tabi ekeji bi
-        Ti a ba agbogoje ohun kan eyi ma nka abo ati ibukun Olorun kuro lori idile.
-        A si fi aye sile fun Satani lati wo inu idile se ise buburu re
-        Kini awon nkan na?
a.     Ese bi agbere tabi pansaga
b.    Aini-fe tabi ikorira
c.     Aini iteriba tabi ibowo
d.    Imotara-eni-nikan
e.     Ija tabi ibinu ati bebe lo
-        Gbogbo eyi je enu ona sisile fun Satan lati wole sinu idile
-        Marku 10:8-9
ADURA
1.    Emi Mimo koto ese bi agbere, ainife,  ibinu ti Satani gbe  fun aya/oko mi lati da idile run, Emi Mimo ba mi di patapata.
2.    Gbogbo igbimo okunkun lori idile mi loruko Jesu Kristi e tuu ka
3.    Emi Mimo jeki nbere si ri oju rere oko/aya mi lati oni lo ni oruko Jesu
4.    Oluwa O, ran emi irepo sarin emi ati oko/aya mi lati oni lo ni oruko Jesu
5.    Oluwa fi igbadun ibukun igbeyawo sinu idile mi lati oni lo l’oruko Jesu.

No comments:

Post a Comment