Sunday 8 June 2014

ORO OLORUN ATI ADURA

AKORI:  AABO LORI IDILE – Eccl. 10:8
Eniti o wa iho ni yio bo sinu re, ati eniti o si nja ogba tutu, ejo yio sib u u san
-        Enyin enia Olorun, o se Pataki lati dabobo ile/idile re
-        Opolopo ni awon ipa lati ode (ita) to ma dide si awon idile Kristieni.
-        O se Pataki lati se ayewo ipile ti idile wa duro le lori
-        Se idile wa kuro lori ife (will) Olorun bi?
-        Se ati gbogoje ohun kan tabi ekeji bi
-        Ti a ba agbogoje ohun kan eyi ma nka abo ati ibukun Olorun kuro lori idile.
-        A si fi aye sile fun Satani lati wo inu idile se ise buburu re
-        Kini awon nkan na?
a.     Ese bi agbere tabi pansaga
b.    Aini-fe tabi ikorira
c.     Aini iteriba tabi ibowo
d.    Imotara-eni-nikan
e.     Ija tabi ibinu ati bebe lo
-        Gbogbo eyi je enu ona sisile fun Satan lati wole sinu idile
-        Marku 10:8-9
ADURA
1.    Emi Mimo koto ese bi agbere, ainife,  ibinu ti Satani gbe  fun aya/oko mi lati da idile run, Emi Mimo ba mi di patapata.
2.    Gbogbo igbimo okunkun lori idile mi loruko Jesu Kristi e tuu ka
3.    Emi Mimo jeki nbere si ri oju rere oko/aya mi lati oni lo ni oruko Jesu
4.    Oluwa O, ran emi irepo sarin emi ati oko/aya mi lati oni lo ni oruko Jesu
5.    Oluwa fi igbadun ibukun igbeyawo sinu idile mi lati oni lo l’oruko Jesu.

IBERE NINU BIBELI (9/06/2014)

1     .KINI JOBU MA A NSE LORI IDILE RE NIWAJU OLORUN LOREKORE?

2.    BAWO NI ABIGELI TI SE DABOBO IDILE RE NI AKOKO OBA DAFIDI?
        SALAYE IBITI ORO NA WA NINU BIBELI

3.    IRU OBINRIN WO NI IYA JAKOBU JE LARIN AWON OMO RE?

(Dahun ibere meta yi daradara, ki o si fi ranse si "ttruthbm2010@yahoo.com" )
Eni marun akoko to ba gba awon ibere yi, yio gba ebun credit N200 kokan)
 .